Home Page >
The Council >
About the Council >
Translation services >
Yoruba
Àjô Redbridge npèsè iÿë tí kò ní àfiwé fún àwôn olùgbé tí wón ÿe
ìrànwö

láti jë kí
Redbridge dára si láti gbé. A npèsè ogunlögõ iÿë fun awôn ènìà
káàkiri agbègbè rè tí ó fi mö:
- Ilé ìwé ati êkö àgbà
- Iÿë fun àwôn ômôdé, àwôn õdö ati çbí, tí ó fi mö ìtöjú ômô
- Awôn iÿë ìtöjú awôn àgbà ní àwùjô
- Ànfànní ati ìtìlëhìn fun àláfíà
- Àmõràn nipa ilé gbígbé
- Awôn ayçyç oní-ìlú
- Ìfi orúkô sílê fun ômô bíbí, ikú ati ìgbéyàwó
- Ilé ìkàwé ati awôn ibùdo eré ìdárayá
- Êgbin ati awôn iÿë àyípadà rê fun àtúnlò
- Iwadi nipa ayè ìgbökõsí ati ìwé ìfà-yèfún
Awôn olùgbìmõ
Awôn olùgbìmõ jë awôn çni ti awôn ènìà yan sí ipò. Wôn nÿé
ìpinsí nípa ìdarí àjô ní orúkô àwùjô. ÿe àwárí awôn ohun ìwífún
nípa olùgbìmõ àröwötó rç lórí adiresi itakun agbaiye (world wide
web) wa tabi pe 020 8708 2353.
Ìlera
Pe 0845 4647 tabi ÿe àbêwò si adiresi itakun agbaiye http://www.nhs.uk/
Fun awôn ohun ìwífún nípa awôn onísègùn alábç, olùtöjú eyín,
olùtöjú ojú, ilé ìtàjà ògùn, awôn ibùdó NHS tí o leè rìnwõ láìpè
wôn tëlê, awôn ibùdó ìjànbà ati pàjáwìrì (A&E) ati ìtöjú awôn
tí nbç ní àwùjô.
Awôn iÿë pàjáwìrì
Ôlôpa
Pe 999 nìkan tí o bá jë pàjáwìrì nítòótó. Fun awôn ibere tí ki
íÿe pàjáwìrì, jõwö pe 020 8478 1123.
Iná (Pàjáwìrì)
Jõwö pe 999
A npèsè awôn iÿë ìtúmõ ati ògbùfõ tí èdè òyìnbó kò bá jé èdè
abínibí rç, tabi tí o bá jé adití tabi o nì ìgbôràn àìpéye.
Ìwé ìrí-ìdí nkan ti o wa ni ìsàlê yi yìó fun ô ni gbogbo awôn
ohun ìwífún tí o nílò láti bèèrè.
Ìwô yíò nílò Adobe Acrobat( fun awôn Ìwé ìrí-ìdí nkan ti pdf)
láti ÿí ìwé ìrí-ìdí nkan ti o wa ní ojú abala yìí.
Lo itôka alá-sopõ ìsàlê yi láti gba èròjà Adobe Acrobat Reader
lôfç láti ori íntánëêtì.
Tí o ba ni ìpe àkíyèsí Kankan ti o nifç láti fun wa nipa awôn
iÿë àjô wa, jõwö kô ìwé ayára bi àsá si email :mailto:customer.cc@redbridge.gov.uk
Redbridge news
Find out about things that are happening in the borough.